Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 3 - المُلك - Page - Juz 29
﴿ٱلَّذِي خَلَقَ سَبۡعَ سَمَٰوَٰتٖ طِبَاقٗاۖ مَّا تَرَىٰ فِي خَلۡقِ ٱلرَّحۡمَٰنِ مِن تَفَٰوُتٖۖ فَٱرۡجِعِ ٱلۡبَصَرَ هَلۡ تَرَىٰ مِن فُطُورٖ ﴾
[المُلك: 3]
﴿الذي خلق سبع سموات طباقا ما ترى في خلق الرحمن من تفاوت﴾ [المُلك: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni tí Ó dá àwọn sánmọ̀ méje ní ìpele ìpele. O ò lè rí àìgúnrégé kan lára ẹ̀dá Àjọkẹ́-ayé. Nítorí náà, wò ó padà, ǹjẹ́ o rí ojú sísán kan (lára sánmọ̀) |