Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 10 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿وَلَا تُطِعۡ كُلَّ حَلَّافٖ مَّهِينٍ ﴾
[القَلَم: 10]
﴿ولا تطع كل حلاف مهين﴾ [القَلَم: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Má ṣe tẹ̀lé gbogbo ẹni tí ìbúra rẹ̀ pọ̀, ẹni yẹpẹrẹ |