Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 29 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿قَالُواْ سُبۡحَٰنَ رَبِّنَآ إِنَّا كُنَّا ظَٰلِمِينَ ﴾
[القَلَم: 29]
﴿قالوا سبحان ربنا إنا كنا ظالمين﴾ [القَلَم: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: "Mímọ́ ni fún Olúwa wa, dájúdájú àwa jẹ́ alábòsí |