Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 28 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿قَالَ أَوۡسَطُهُمۡ أَلَمۡ أَقُل لَّكُمۡ لَوۡلَا تُسَبِّحُونَ ﴾
[القَلَم: 28]
﴿قال أوسطهم ألم أقل لكم لولا تسبحون﴾ [القَلَم: 28]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni t’ó dúró déédé jùlọ nínú wọn sọ pé: "Ṣé èmi kò sọ fun yín pé ẹ̀yin kò ṣe ṣàfọ̀mọ́ fún Allāhu (pé "a máa kórè oko wa, ’in ṣā ’Allāhu) |