Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 139 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿إِنَّ هَٰٓؤُلَآءِ مُتَبَّرٞ مَّا هُمۡ فِيهِ وَبَٰطِلٞ مَّا كَانُواْ يَعۡمَلُونَ ﴾
[الأعرَاف: 139]
﴿إن هؤلاء متبر ما هم فيه وباطل ما كانوا يعملون﴾ [الأعرَاف: 139]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn wọ̀nyí máa parun lórí ohun tí wọ́n ń ṣe (yìí). Irọ́ sì ni ohun tí wọ́n ń ṣe níṣẹ́.” |