Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 140 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿قَالَ أَغَيۡرَ ٱللَّهِ أَبۡغِيكُمۡ إِلَٰهٗا وَهُوَ فَضَّلَكُمۡ عَلَى ٱلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الأعرَاف: 140]
﴿قال أغير الله أبغيكم إلها وهو فضلكم على العالمين﴾ [الأعرَاف: 140]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì) Mūsā sọ pé: "Ṣé kí èmi tún ba yín wá ọlọ́hun kan tí ẹ̀yin yóò máa jọ́sìn fún lẹ́yìn Allāhu ni? Òun l’Ó sì ṣe àjùlọ oore fun yín lórí àwọn ẹ̀dá (àsìkò yín) |