Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 7 - الأعرَاف - Page - Juz 8
﴿فَلَنَقُصَّنَّ عَلَيۡهِم بِعِلۡمٖۖ وَمَا كُنَّا غَآئِبِينَ ﴾
[الأعرَاف: 7]
﴿فلنقصن عليهم بعلم وما كنا غائبين﴾ [الأعرَاف: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A óò ròyìn (iṣẹ́ ọwọ́ wọn) fún wọn pẹ̀lú ìmọ̀. Àwa kò ṣàì wà pẹ̀lú wọn (pẹ̀lú ìmọ̀) |