Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma‘arij ayat 17 - المَعَارج - Page - Juz 29
﴿تَدۡعُواْ مَنۡ أَدۡبَرَ وَتَوَلَّىٰ ﴾
[المَعَارج: 17]
﴿تدعو من أدبر وتولى﴾ [المَعَارج: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Iná) yó máa ké sí ẹni t’ó kẹ̀yìn sí (ìgbágbọ́ òdodo), tí ó sì takété sí i |