Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma‘arij ayat 31 - المَعَارج - Page - Juz 29
﴿فَمَنِ ٱبۡتَغَىٰ وَرَآءَ ذَٰلِكَ فَأُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡعَادُونَ ﴾
[المَعَارج: 31]
﴿فمن ابتغى وراء ذلك فأولئك هم العادون﴾ [المَعَارج: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni nítorí náà, ẹni kẹ́ni t’ó bá ń wá n̄ǹkan mìíràn lẹ́yìn ìyẹn, àwọn wọ̀nyẹn ni àwọn olùtayọ-ẹnu àlà |