Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma‘arij ayat 38 - المَعَارج - Page - Juz 29
﴿أَيَطۡمَعُ كُلُّ ٱمۡرِيٕٖ مِّنۡهُمۡ أَن يُدۡخَلَ جَنَّةَ نَعِيمٖ ﴾
[المَعَارج: 38]
﴿أيطمع كل امرئ منهم أن يدخل جنة نعيم﴾ [المَعَارج: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé ẹnì kọ̀ọ̀kan nínú wọn ń jẹ̀rankàn pé A óò mú òun wọ inú Ọgbà Ìdẹ̀ra ni |