Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma‘arij ayat 40 - المَعَارج - Page - Juz 29
﴿فَلَآ أُقۡسِمُ بِرَبِّ ٱلۡمَشَٰرِقِ وَٱلۡمَغَٰرِبِ إِنَّا لَقَٰدِرُونَ ﴾
[المَعَارج: 40]
﴿فلا أقسم برب المشارق والمغارب إنا لقادرون﴾ [المَعَارج: 40]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, Èmi ń búra pẹ̀lú Olúwa àwọn ibùyọ òòrùn àti àwọn ibùwọ̀ òòrùn , dájúdájú Àwa ni Alágbára |