Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma‘arij ayat 41 - المَعَارج - Page - Juz 29
﴿عَلَىٰٓ أَن نُّبَدِّلَ خَيۡرٗا مِّنۡهُمۡ وَمَا نَحۡنُ بِمَسۡبُوقِينَ ﴾
[المَعَارج: 41]
﴿على أن نبدل خيرا منهم وما نحن بمسبوقين﴾ [المَعَارج: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni láti lè fi àwọn t’ó dára jù wọ́n lọ pààrọ̀ wọn. Kò sì sí ẹni t’ó lè kó agara bá Wa |