Quran with Yoruba translation - Surah Nuh ayat 26 - نُوح - Page - Juz 29
﴿وَقَالَ نُوحٞ رَّبِّ لَا تَذَرۡ عَلَى ٱلۡأَرۡضِ مِنَ ٱلۡكَٰفِرِينَ دَيَّارًا ﴾
[نُوح: 26]
﴿وقال نوح رب لا تذر على الأرض من الكافرين ديارا﴾ [نُوح: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì) Nūh tún sọ pé: "Olúwa mi, má ṣe fi ẹnì kan kan nínú àwọn aláìgbàgbọ́ sílẹ̀ lórí ilẹ̀ |