×

Ati pe igbakigba ti mo ba pe won pe ki O le 71:7 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Nuh ⮕ (71:7) ayat 7 in Yoruba

71:7 Surah Nuh ayat 7 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Nuh ayat 7 - نُوح - Page - Juz 29

﴿وَإِنِّي كُلَّمَا دَعَوۡتُهُمۡ لِتَغۡفِرَ لَهُمۡ جَعَلُوٓاْ أَصَٰبِعَهُمۡ فِيٓ ءَاذَانِهِمۡ وَٱسۡتَغۡشَوۡاْ ثِيَابَهُمۡ وَأَصَرُّواْ وَٱسۡتَكۡبَرُواْ ٱسۡتِكۡبَارٗا ﴾
[نُوح: 7]

Ati pe igbakigba ti mo ba pe won pe ki O le forijin won, won n fi omonika won di eti won, won n yiso won bori, won n taku (sori ese), won si n segberaga gan-an

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وإني كلما دعوتهم لتغفر لهم جعلوا أصابعهم في آذانهم واستغشوا ثيابهم وأصروا, باللغة اليوربا

﴿وإني كلما دعوتهم لتغفر لهم جعلوا أصابعهم في آذانهم واستغشوا ثيابهم وأصروا﴾ [نُوح: 7]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àti pé ìgbàkígbà tí mo bá pè wọ́n pé kí O lè foríjìn wọ́n, wọ́n ń fi ọmọníka wọn dí etí wọn, wọ́n ń yíṣọ wọn borí, wọ́n ń takú (sórí ẹ̀ṣẹ̀), wọ́n sì ń ṣègbéraga gan-an
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek