Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jinn ayat 20 - الجِن - Page - Juz 29
﴿قُلۡ إِنَّمَآ أَدۡعُواْ رَبِّي وَلَآ أُشۡرِكُ بِهِۦٓ أَحَدٗا ﴾ 
[الجِن: 20]
﴿قل إنما أدعو ربي ولا أشرك به أحدا﴾ [الجِن: 20]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Olúwa mi ni mò ń pè. Àti pé èmi kò níí sọ ẹnì kan kan di akẹgbẹ́ fún Un |