Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jinn ayat 22 - الجِن - Page - Juz 29
﴿قُلۡ إِنِّي لَن يُجِيرَنِي مِنَ ٱللَّهِ أَحَدٞ وَلَنۡ أَجِدَ مِن دُونِهِۦ مُلۡتَحَدًا ﴾
[الجِن: 22]
﴿قل إني لن يجيرني من الله أحد ولن أجد من دونه ملتحدا﴾ [الجِن: 22]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Dájúdájú èmi, kò sí ẹnì kan t’ó lè gbà mí là lọ́dọ̀ Allāhu. Èmi kò sì rí ibùsásí kan lẹ́yìn Rẹ̀ |