×

Afi (ki ng se) ikede (t’o wa) lati odo Allahu ati awon 72:23 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Jinn ⮕ (72:23) ayat 23 in Yoruba

72:23 Surah Al-Jinn ayat 23 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jinn ayat 23 - الجِن - Page - Juz 29

﴿إِلَّا بَلَٰغٗا مِّنَ ٱللَّهِ وَرِسَٰلَٰتِهِۦۚ وَمَن يَعۡصِ ٱللَّهَ وَرَسُولَهُۥ فَإِنَّ لَهُۥ نَارَ جَهَنَّمَ خَٰلِدِينَ فِيهَآ أَبَدًا ﴾
[الجِن: 23]

Afi (ki ng se) ikede (t’o wa) lati odo Allahu ati awon ise Re (t’O fi ran mi). Enikeni t’o ba yapa Allahu ati Ojise Re, dajudaju ina Jahanamo n be fun un. Olusegbere ni won ninu re titi laelae

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إلا بلاغا من الله ورسالاته ومن يعص الله ورسوله فإن له نار, باللغة اليوربا

﴿إلا بلاغا من الله ورسالاته ومن يعص الله ورسوله فإن له نار﴾ [الجِن: 23]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àfi (kí n̄g ṣe) ìkédé (t’ó wá) láti ọ̀dọ̀ Allāhu àti àwọn iṣẹ́ Rẹ̀ (t’Ó fi rán mi). Ẹnikẹ́ni t’ó bá yapa Allāhu àti Òjíṣẹ́ Rẹ̀, dájúdájú iná Jahanamọ ń bẹ fún un. Olùṣegbére ni wọ́n nínú rẹ̀ títí láéláé
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek