Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qiyamah ayat 5 - القِيَامة - Page - Juz 29
﴿بَلۡ يُرِيدُ ٱلۡإِنسَٰنُ لِيَفۡجُرَ أَمَامَهُۥ ﴾
[القِيَامة: 5]
﴿بل يريد الإنسان ليفجر أمامه﴾ [القِيَامة: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣùgbọ́n ènìyàn gbèrò láti pe (Ọjọ́ Àjíǹde) t’ó ń bẹ níwájú rẹ̀ nírọ́ |