Quran with Yoruba translation - Surah An-Nazi‘at ayat 10 - النَّازعَات - Page - Juz 30
﴿يَقُولُونَ أَءِنَّا لَمَرۡدُودُونَ فِي ٱلۡحَافِرَةِ ﴾
[النَّازعَات: 10]
﴿يقولون أئنا لمردودون في الحافرة﴾ [النَّازعَات: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn yóò wí pé: "Ṣé Wọ́n tún máa dá wa padà sí ìbẹ̀rẹ̀ ìṣẹ̀mí (bíi tayé ni) |