Quran with Yoruba translation - Surah An-Nazi‘at ayat 27 - النَّازعَات - Page - Juz 30
﴿ءَأَنتُمۡ أَشَدُّ خَلۡقًا أَمِ ٱلسَّمَآءُۚ بَنَىٰهَا ﴾
[النَّازعَات: 27]
﴿أأنتم أشد خلقا أم السماء بناها﴾ [النَّازعَات: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé ẹ̀yin lẹ lágbára jùlọ ní ìṣẹ̀dá ni tàbí sánmọ̀ tí Allāhu mọ |