Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anfal ayat 18 - الأنفَال - Page - Juz 9
﴿ذَٰلِكُمۡ وَأَنَّ ٱللَّهَ مُوهِنُ كَيۡدِ ٱلۡكَٰفِرِينَ ﴾
[الأنفَال: 18]
﴿ذلكم وأن الله موهن كيد الكافرين﴾ [الأنفَال: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn (báyẹn). Dájúdájú Allāhu máa sọ ète àwọn aláìgbàgbọ́ di lílẹ |