Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anfal ayat 51 - الأنفَال - Page - Juz 10
﴿ذَٰلِكَ بِمَا قَدَّمَتۡ أَيۡدِيكُمۡ وَأَنَّ ٱللَّهَ لَيۡسَ بِظَلَّٰمٖ لِّلۡعَبِيدِ ﴾
[الأنفَال: 51]
﴿ذلك بما قدمت أيديكم وأن الله ليس بظلام للعبيد﴾ [الأنفَال: 51]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn nítorí ohun tí ọwọ́ yín tì ṣíwájú. Àti pé dájúdájú Allāhu kò níí ṣe àbòsí fún àwọn ẹrú (Rẹ̀) |