Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anfal ayat 8 - الأنفَال - Page - Juz 9
﴿لِيُحِقَّ ٱلۡحَقَّ وَيُبۡطِلَ ٱلۡبَٰطِلَ وَلَوۡ كَرِهَ ٱلۡمُجۡرِمُونَ ﴾
[الأنفَال: 8]
﴿ليحق الحق ويبطل الباطل ولو كره المجرمون﴾ [الأنفَال: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni nítorí kí (Allāhu) lè fi òdodo (’Islām) rinlẹ̀ ní òdodo, kí Ó sì lè paná irọ́ (ìbọ̀rìṣà), àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ (ọ̀ṣẹbọ) ìbáà kórira rẹ̀ |