Quran with Yoruba translation - Surah Al-MuTaffifin ayat 15 - المُطَففين - Page - Juz 30
﴿كـَلَّآ إِنَّهُمۡ عَن رَّبِّهِمۡ يَوۡمَئِذٖ لَّمَحۡجُوبُونَ ﴾
[المُطَففين: 15]
﴿كلا إنهم عن ربهم يومئذ لمحجوبون﴾ [المُطَففين: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti òdodo, dájúdájú wọn yóò wà nínú gàgá, wọn kò sì níí rí Olúwa wọn ní ọjọ́ yẹn |