Quran with Yoruba translation - Surah Al-MuTaffifin ayat 29 - المُطَففين - Page - Juz 30
﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ أَجۡرَمُواْ كَانُواْ مِنَ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ يَضۡحَكُونَ ﴾
[المُطَففين: 29]
﴿إن الذين أجرموا كانوا من الذين آمنوا يضحكون﴾ [المُطَففين: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn t’ó dẹ́ṣẹ̀, wọ́n máa ń fi àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo rẹ́rìn-ín |