Quran with Yoruba translation - Surah Al-Inshiqaq ayat 21 - الانشِقَاق - Page - Juz 30
﴿وَإِذَا قُرِئَ عَلَيۡهِمُ ٱلۡقُرۡءَانُ لَا يَسۡجُدُونَۤ۩ ﴾
[الانشِقَاق: 21]
﴿وإذا قرئ عليهم القرآن لا يسجدون﴾ [الانشِقَاق: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí wọ́n bá sì ké al-Ƙur’ān fún wọn, wọn kò níí forí kanlẹ̀ |