Quran with Yoruba translation - Surah Al-Inshiqaq ayat 25 - الانشِقَاق - Page - Juz 30
﴿إِلَّا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَمِلُواْ ٱلصَّٰلِحَٰتِ لَهُمۡ أَجۡرٌ غَيۡرُ مَمۡنُونِۭ ﴾
[الانشِقَاق: 25]
﴿إلا الذين آمنوا وعملوا الصالحات لهم أجر غير ممنون﴾ [الانشِقَاق: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àyàfi àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n sì ṣe àwọn iṣẹ́ rere, ẹ̀san tí kò níí pin ń bẹ fún wọn |