Quran with Yoruba translation - Surah Al-Buruj ayat 9 - البُرُوج - Page - Juz 30
﴿ٱلَّذِي لَهُۥ مُلۡكُ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۚ وَٱللَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيۡءٖ شَهِيدٌ ﴾
[البُرُوج: 9]
﴿الذي له ملك السموات والأرض والله على كل شيء شهيد﴾ [البُرُوج: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni tí Ó ni ìjọba àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀. Allāhu sì ni Ẹlẹ́rìí lórí gbogbo n̄ǹkan |