Quran with Yoruba translation - Surah Al-Buruj ayat 8 - البُرُوج - Page - Juz 30
﴿وَمَا نَقَمُواْ مِنۡهُمۡ إِلَّآ أَن يُؤۡمِنُواْ بِٱللَّهِ ٱلۡعَزِيزِ ٱلۡحَمِيدِ ﴾
[البُرُوج: 8]
﴿وما نقموا منهم إلا أن يؤمنوا بالله العزيز الحميد﴾ [البُرُوج: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sì sí kiní kan tí wọ́n torí rẹ̀ jẹ wọ́n níyà bí kò ṣe pé wọ́n ní ìgbàgbọ́ òdodo nínú Allāhu, Alágbára, Ọlọ́pẹ́ |