Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fajr ayat 22 - الفَجر - Page - Juz 30
﴿وَجَآءَ رَبُّكَ وَٱلۡمَلَكُ صَفّٗا صَفّٗا ﴾
[الفَجر: 22]
﴿وجاء ربك والملك صفا صفا﴾ [الفَجر: 22]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (tí) Olúwa rẹ dé pẹ̀lú àwọn mọlāika ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́ ọ̀wọ̀ọ̀wọ́ |