Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fajr ayat 21 - الفَجر - Page - Juz 30
﴿كـَلَّآۖ إِذَا دُكَّتِ ٱلۡأَرۡضُ دَكّٗا دَكّٗا ﴾
[الفَجر: 21]
﴿كلا إذا دكت الأرض دكا دكا﴾ [الفَجر: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Rárá, (kò yẹ kó rí bẹ́ẹ̀). Nígbà tí wọ́n bá mi ilẹ̀ tìtì ní mímì tìtì (t’ó rún wómúwómú, tí kò sí kòtò, tí kò sí gelemọ) |