Quran with Yoruba translation - Surah At-Taubah ayat 22 - التوبَة - Page - Juz 10
﴿خَٰلِدِينَ فِيهَآ أَبَدًاۚ إِنَّ ٱللَّهَ عِندَهُۥٓ أَجۡرٌ عَظِيمٞ ﴾
[التوبَة: 22]
﴿خالدين فيها أبدا إن الله عنده أجر عظيم﴾ [التوبَة: 22]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olùṣegbére ni wọ́n nínú rẹ̀ títí láéláé. Dájúdájú Allāhu, ọ̀dọ̀ Rẹ̀ ni ẹ̀san ńlá wà |