×

Ti o ba je pe won jade pelu yin, won ko nii 9:47 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah At-Taubah ⮕ (9:47) ayat 47 in Yoruba

9:47 Surah At-Taubah ayat 47 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah At-Taubah ayat 47 - التوبَة - Page - Juz 10

﴿لَوۡ خَرَجُواْ فِيكُم مَّا زَادُوكُمۡ إِلَّا خَبَالٗا وَلَأَوۡضَعُواْ خِلَٰلَكُمۡ يَبۡغُونَكُمُ ٱلۡفِتۡنَةَ وَفِيكُمۡ سَمَّٰعُونَ لَهُمۡۗ وَٱللَّهُ عَلِيمُۢ بِٱلظَّٰلِمِينَ ﴾
[التوبَة: 47]

Ti o ba je pe won jade pelu yin, won ko nii kun yin afi pelu ibaje. Won yo si sare maa da rukerudo sile laaarin yin, ti won yoo maa ko yin sinu iyonu. Ati pe won ni olugboro fun won laaarin yin. Allahu si ni Onimo nipa awon alabosi

❮ Previous Next ❯

ترجمة: لو خرجوا فيكم ما زادوكم إلا خبالا ولأوضعوا خلالكم يبغونكم الفتنة وفيكم, باللغة اليوربا

﴿لو خرجوا فيكم ما زادوكم إلا خبالا ولأوضعوا خلالكم يبغونكم الفتنة وفيكم﴾ [التوبَة: 47]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Tí ó bá jẹ́ pé wọ́n jáde pẹ̀lú yín, wọn kò níí kun yín àfi pẹ̀lú ìbàjẹ́. Wọn yó sì sáré máa dá rúkèrúdò sílẹ̀ láààrin yín, tí wọn yóò máa ko yín sínú ìyọnu. Àti pé wọ́n ní olùgbọ́rọ̀ fún wọn láààrin yín. Allāhu sì ni Onímọ̀ nípa àwọn alábòsí
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek