Quran with Yoruba translation - Surah At-Taubah ayat 76 - التوبَة - Page - Juz 10
﴿فَلَمَّآ ءَاتَىٰهُم مِّن فَضۡلِهِۦ بَخِلُواْ بِهِۦ وَتَوَلَّواْ وَّهُم مُّعۡرِضُونَ ﴾
[التوبَة: 76]
﴿فلما آتاهم من فضله بخلوا به وتولوا وهم معرضون﴾ [التوبَة: 76]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àmọ́ nígbà tí Ó fún wọn nínú oore-àjùlọ Rẹ̀, wọ́n ṣahun sí I. Wọ́n pẹ̀yìn dà, wọ́n sì ń gbúnrí (láti náwó fẹ́sìn) |