Quran with Yoruba translation - Surah At-Taubah ayat 89 - التوبَة - Page - Juz 10
﴿أَعَدَّ ٱللَّهُ لَهُمۡ جَنَّٰتٖ تَجۡرِي مِن تَحۡتِهَا ٱلۡأَنۡهَٰرُ خَٰلِدِينَ فِيهَاۚ ذَٰلِكَ ٱلۡفَوۡزُ ٱلۡعَظِيمُ ﴾
[التوبَة: 89]
﴿أعد الله لهم جنات تجري من تحتها الأنهار خالدين فيها ذلك الفوز﴾ [التوبَة: 89]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu ti pèsè sílẹ̀ dè wọ́n àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra kan tí odò ń ṣàn ní ìsàlẹ̀ rẹ̀. Olùṣegbére ni wọ́n nínú rẹ̀. Ìyẹn ni èrèǹjẹ ńlá |