×

Awon alawaawi ninu awon Larubawa oko wa (ba o) nitori ki won 9:90 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah At-Taubah ⮕ (9:90) ayat 90 in Yoruba

9:90 Surah At-Taubah ayat 90 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah At-Taubah ayat 90 - التوبَة - Page - Juz 10

﴿وَجَآءَ ٱلۡمُعَذِّرُونَ مِنَ ٱلۡأَعۡرَابِ لِيُؤۡذَنَ لَهُمۡ وَقَعَدَ ٱلَّذِينَ كَذَبُواْ ٱللَّهَ وَرَسُولَهُۥۚ سَيُصِيبُ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ مِنۡهُمۡ عَذَابٌ أَلِيمٞ ﴾
[التوبَة: 90]

Awon alawaawi ninu awon Larubawa oko wa (ba o) nitori ki won le yonda (ijokoo sile) fun won. Awon t’o si pe oro Allahu ati oro Ojise niro naa jokoo sile. Iya eleta-elero yo si fowo ba awon t’o sai gbagbo ninu won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وجاء المعذرون من الأعراب ليؤذن لهم وقعد الذين كذبوا الله ورسوله سيصيب, باللغة اليوربا

﴿وجاء المعذرون من الأعراب ليؤذن لهم وقعد الذين كذبوا الله ورسوله سيصيب﴾ [التوبَة: 90]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn aláwàáwí nínú àwọn Lárúbáwá oko wá (bá ọ) nítorí kí wọ́n lè yọ̀ǹda (ìjókòó sílé) fún wọn. Àwọn t’ó sì pe ọ̀rọ̀ Allāhu àti ọ̀rọ̀ Òjíṣẹ́ nírọ́ náà jókòó sílé. Ìyà ẹlẹ́ta-eléro yó sì fọwọ́ ba àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ nínú wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek