Quran with Yoruba translation - Surah Al-Lail ayat 19 - اللَّيل - Page - Juz 30
﴿وَمَا لِأَحَدٍ عِندَهُۥ مِن نِّعۡمَةٖ تُجۡزَىٰٓ ﴾
[اللَّيل: 19]
﴿وما لأحد عنده من نعمة تجزى﴾ [اللَّيل: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sì sí oore ìdẹ̀ra kan tí (ó ní lọ́kàn) láti gbà ní ẹ̀san ní ọ̀dọ̀ ẹnikẹ́ni |