Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 44 - يُونس - Page - Juz 11
﴿إِنَّ ٱللَّهَ لَا يَظۡلِمُ ٱلنَّاسَ شَيۡـٔٗا وَلَٰكِنَّ ٱلنَّاسَ أَنفُسَهُمۡ يَظۡلِمُونَ ﴾
[يُونس: 44]
﴿إن الله لا يظلم الناس شيئا ولكن الناس أنفسهم يظلمون﴾ [يُونس: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Allāhu kò níí fí kiní kan ṣàbòsí sí ènìyàn. Ṣùgbọ́n ènìyàn ń ṣàbòsí sí ẹ̀mí ara wọn |