Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘adiyat ayat 9 - العَاديَات - Page - Juz 30
﴿۞ أَفَلَا يَعۡلَمُ إِذَا بُعۡثِرَ مَا فِي ٱلۡقُبُورِ ﴾
[العَاديَات: 9]
﴿أفلا يعلم إذا بعثر ما في القبور﴾ [العَاديَات: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé kò mọ̀ pé nígbà tí wọ́n bá tú ohun t’ó wà nínú sàréè jáde (fún àjíǹde) |