Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 106 - هُود - Page - Juz 12
﴿فَأَمَّا ٱلَّذِينَ شَقُواْ فَفِي ٱلنَّارِ لَهُمۡ فِيهَا زَفِيرٞ وَشَهِيقٌ ﴾
[هُود: 106]
﴿فأما الذين شقوا ففي النار لهم فيها زفير وشهيق﴾ [هُود: 106]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti àwọn t’ó bá ṣorí burúkú, wọn yóò wà nínú Iná. Wọn yóò máa gbin tòò, wọn yó sì máa ké tòò |