Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 83 - هُود - Page - Juz 12
﴿مُّسَوَّمَةً عِندَ رَبِّكَۖ وَمَا هِيَ مِنَ ٱلظَّٰلِمِينَ بِبَعِيدٖ ﴾
[هُود: 83]
﴿مسومة عند ربك وما هي من الظالمين ببعيد﴾ [هُود: 83]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àwọn òkúta náà) ti ní àmì (orúkọ ẹnì kọ̀ọ̀kan wọn lára) láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ. Wọn kò sì jìnnà sí àwọn alábòsí |