Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 103 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿وَمَآ أَكۡثَرُ ٱلنَّاسِ وَلَوۡ حَرَصۡتَ بِمُؤۡمِنِينَ ﴾
[يُوسُف: 103]
﴿وما أكثر الناس ولو حرصت بمؤمنين﴾ [يُوسُف: 103]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìwọ ìbáà ṣojú kòkòrò (ìgbàlà wọn), ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ènìyàn ni kò níí gbàgbọ́ |