Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 104 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿وَمَا تَسۡـَٔلُهُمۡ عَلَيۡهِ مِنۡ أَجۡرٍۚ إِنۡ هُوَ إِلَّا ذِكۡرٞ لِّلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[يُوسُف: 104]
﴿وما تسألهم عليه من أجر إن هو إلا ذكر للعالمين﴾ [يُوسُف: 104]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìwọ kò sì bi wọ́n léèrè owó-ọ̀yà kan lórí rẹ̀. Kò sì jẹ́ kiní kan bí kò ṣe ìrántí fún gbogbo ẹ̀dá |