Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 105 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿وَكَأَيِّن مِّنۡ ءَايَةٖ فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ يَمُرُّونَ عَلَيۡهَا وَهُمۡ عَنۡهَا مُعۡرِضُونَ ﴾
[يُوسُف: 105]
﴿وكأين من آية في السموات والأرض يمرون عليها وهم عنها معرضون﴾ [يُوسُف: 105]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé mélòó mélòó nínú àwọn àmì tí ń bẹ ní sánmọ̀ àti ní orí ilẹ̀ tí wọ́n ń ré kọjá lórí rẹ̀, tí wọ́n sì ń gbúnrí kúrò níbẹ̀ |