Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 106 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿وَمَا يُؤۡمِنُ أَكۡثَرُهُم بِٱللَّهِ إِلَّا وَهُم مُّشۡرِكُونَ ﴾
[يُوسُف: 106]
﴿وما يؤمن أكثرهم بالله إلا وهم مشركون﴾ [يُوسُف: 106]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn sì ni kò níí gba Allāhu gbọ́ ní òdodo àfi kí wọ́n tún máa ṣẹbọ |