Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 92 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿قَالَ لَا تَثۡرِيبَ عَلَيۡكُمُ ٱلۡيَوۡمَۖ يَغۡفِرُ ٱللَّهُ لَكُمۡۖ وَهُوَ أَرۡحَمُ ٱلرَّٰحِمِينَ ﴾
[يُوسُف: 92]
﴿قال لا تثريب عليكم اليوم يغفر الله لكم وهو أرحم الراحمين﴾ [يُوسُف: 92]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: "Kò sí ìbáwí fun yín ní òní. Allāhu yóò foríjìn yín. Òun sì ni Aláàánú-jùlọ nínú àwọn aláàánú |