Quran with Yoruba translation - Surah Ibrahim ayat 16 - إبراهِيم - Page - Juz 13
﴿مِّن وَرَآئِهِۦ جَهَنَّمُ وَيُسۡقَىٰ مِن مَّآءٖ صَدِيدٖ ﴾
[إبراهِيم: 16]
﴿من ورائه جهنم ويسقى من ماء صديد﴾ [إبراهِيم: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Iná Jahanamọ ń bẹ lẹ́yìn (ìparun) rẹ̀; A ó sì máa fún un ní omi àwọyúnwẹ̀jẹ̀ mu |