×

Awon t’o n feran isemi aye ju torun, ti won n seri 14:3 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ibrahim ⮕ (14:3) ayat 3 in Yoruba

14:3 Surah Ibrahim ayat 3 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ibrahim ayat 3 - إبراهِيم - Page - Juz 13

﴿ٱلَّذِينَ يَسۡتَحِبُّونَ ٱلۡحَيَوٰةَ ٱلدُّنۡيَا عَلَى ٱلۡأٓخِرَةِ وَيَصُدُّونَ عَن سَبِيلِ ٱللَّهِ وَيَبۡغُونَهَا عِوَجًاۚ أُوْلَٰٓئِكَ فِي ضَلَٰلِۭ بَعِيدٖ ﴾
[إبراهِيم: 3]

Awon t’o n feran isemi aye ju torun, ti won n seri awon eniyan kuro loju ona (esin) Allahu, won si n fe ko wo; awon wonyen wa ninu isina t’o jinna

❮ Previous Next ❯

ترجمة: الذين يستحبون الحياة الدنيا على الآخرة ويصدون عن سبيل الله ويبغونها عوجا, باللغة اليوربا

﴿الذين يستحبون الحياة الدنيا على الآخرة ويصدون عن سبيل الله ويبغونها عوجا﴾ [إبراهِيم: 3]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn t’ó ń fẹ́ràn ìṣẹ̀mí ayé ju tọ̀run, tí wọ́n ń ṣẹ́rí àwọn ènìyàn kúrò lójú ọ̀nà (ẹ̀sìn) Allāhu, wọ́n sì ń fẹ́ kó wọ́; àwọn wọ̀nyẹn wà nínú ìṣìnà t’ó jìnnà
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek