Quran with Yoruba translation - Surah Ibrahim ayat 49 - إبراهِيم - Page - Juz 13
﴿وَتَرَى ٱلۡمُجۡرِمِينَ يَوۡمَئِذٖ مُّقَرَّنِينَ فِي ٱلۡأَصۡفَادِ ﴾
[إبراهِيم: 49]
﴿وترى المجرمين يومئذ مقرنين في الأصفاد﴾ [إبراهِيم: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni O sì máa rí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ọjọ́ yẹn, tí wọn yóò so wọ́n papọ̀ mọ́ra wọn sínú sẹ́kẹ́sẹkẹ̀ |