Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 20 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَجَعَلۡنَا لَكُمۡ فِيهَا مَعَٰيِشَ وَمَن لَّسۡتُمۡ لَهُۥ بِرَٰزِقِينَ ﴾
[الحِجر: 20]
﴿وجعلنا لكم فيها معايش ومن لستم له برازقين﴾ [الحِجر: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A ṣe ọ̀nà ìjẹ-ìmu sínú (ilé ayé) fun ẹ̀yin àti àwọn tí ẹ̀yin kò lè pèsè fún |